DSC_1327.jpeg

Obinrin àmó

Obinrin àmó

Obinrin àmó (obinrin tí a fi àmó ṣe ní èdè Yorùbá) jé àkòójì àkójàpò ohun íkan tí mo fi rè tè sí ibi àwòsé àmó ní ìlú Ìganran (Ní ilẹ̀ Yorùbá) géè bí ipàdé ògún àsíkò mi ní G.A.S. Foundation.

English version here.

Obinrin àmó

〰️

Obinrin àmó 〰️


1

Òrò kan: Àná (Yesterday)
Àwòn ikoko ti oni yio duro dè àkókò míràn fún iyipada látío wá.
Àná jé pàtákí nígbà tí a bá fé máa tónjú ònà isé náà.




Ohun isé: Ewé Móra
(Leaves of the Mora tree)
Awòn ewé igi Móra tí a máa nlo fún didán àgbárá àwòn ikoko.

Ọ̀gbọ́n ìrán:

Ìmòlé kan:
Bí owó tí mo máa san fún isé àwòn obinrin òòn yìí àti àmó tí mo rà ti n jérèdé, mo béèrè —
Kí ni ìyàlénú isé ònà?
Kí ni iye àwọn ọjà tí a máa fi isé ọwọ wà káàkiri àwọn àwòn ábèni?
Wón kò mọ ìgbà tí isé náà bèèrè. Sugbon wón máa n reti pé, nígbà tí àwọn ọdọ bá tè sí ilé èkò ní ilé-ìwé, wón máa tònjú isé náà.
Báwo ni a ṣe lè gbàgbé? Báwo ni a ṣe lè yà ilé àwòn ikoko?
Ilé ìlé àti àmó tí ilé ayé fi fún wón. Ròró sugbon lagbara. Ohun ti a nife si isé pẹlu.
Ilé ayé pupa tí ina máa yí pada sí pupa. 10% àwọn ikoko n dá sí.
Nítorí pé ina kò ní àànú. Ina tí mo fẹràn láti ri ní Ọjọ́ Àìkú.
Àwòn ikoko fún isé àdúrà, fún Agbo. Èfè ló fún àtijó, àwọn agogo ikoko, abbl.
Wón máa n se àwòn onígun tuntun tí àwòn oníbàárà bá fé é. Bí kò bá rí bẹ, àwòn onígun atijó ló tàkún.
Nigba tí mo jókòó láti se, mo rí ilé.
Lékan si.
Lékan si ní ìlú òké tí èdè àmó mù mí sòrí àwọn aláìbámò.
Níbi tí mo fi ara mọ.


2

Òrò kan: Ina (fire)
Àdúrà wa sí ina kí ó fi orire ké wa.
Ọba Ina, jé kí o so ire wá.



Ohun isé: Ogbo (firing prop)
Àwòn ìgbàlé àmó tí a n lo. Wón fi fún dídé àwọn ikoko ki àwọn igi má bàa jó wọn pátápátá.

Ọ̀gbọ́n ìrán:

Ìmòlé kan:
Mo ti rí i ní ilé ìwé.
Ṣùgbọ́n mi ò tí rí i ní ojú ara.
Isé ina ikoko dára púpọ́. Ó wà ní àbàyàn.
Ṣùgbọ́n kìí ṣàwòn ina náà nìkan. 
Àwòn iná náà máa fi àyè tùntùn fun ikoko, ayé láé.
Ó jé ìlòdé. Isé àkòpò.
Ohun tó se dárà.
Loni, iṣẹ yìí jẹ fún obinrin méjì tí àwọn ọdọ àti àwọn obinrin mìíràn ràn lòwò nípa mímu igi àti ikoko wá.
Obinrin méjì.
Ọjọ métàdínlógún fún se.
Ẹgbèrà ikoko tí wón kò le kà sójú míràn. Nígbà tí wón bá ti mọ ohun tí ina ti já.
Wón fi wá sí ilé.
Ilé ayé gbóná.
Àwòn obinrin náà sùn jì.
Àwòn ikoko pupa tí wón jẹ òkùnkùn tùmí lo.
Ó dáàrò.


INTERLUDE: Èyà mẹwàá tí mo fẹ́ràn nípa ina

Bí ó ti n jó Gbigbona rẹ
Àwọn àwọ tó yí pada gégé bí ojoro
Bí ó ti jó wá sí oju fọto
Bí oúnjẹ tí a sè pẹ́lú ina ṣe yàtọ
Àwọn ibi gbígbóná ní Pyrenees
Ìròyìn àbẹ ilé baba mi ní Panticosa
Jíjé Aries
Bí a ti máa jíròrò ní agbègbè rẹ
Bí ó ti yí àmó pada sí ohun èlò tí a lè fi lo


3

Òrò kan: Àmó (clay)
Orísun tí kò lò pin,
tí ń dáàbò bò isẹ́ wọn.





Ohun isẹ́: Ọkọ́ (Hoe)
Kéré díẹ̀ ju àwọn ohun ìrìnrìn isẹ́ mìíràn lọ, tí a fi ń gbẹ̀ àmó,
kí a sì lè darí èyí tí a ń pọn mọ omi.

Ọ̀gbọ́n ìrán:

Ìmòlè kan:
Isẹ́ tí ó nira lábẹ́ oorun.
Ẹyìn ọwọ́ mi gbóná lójú òde àti lójú inú.
Ṣùgbọ́n wọ́n ń gbẹ̀ yí séwò lóǹgà.
"Kò rọrùn," ọ̀kan nínú wọn sọ.
Mo ti máa sọ pé ọ̀kan nínú àwọn nǹkan tí mo fẹ́ràn jù nípa isẹ́ àmó,
ni ìbátan rẹ̀ pẹ̀lú ọwọ́.
Ọ̀rọ̀ àìsòro.
Lónìí, ẹsẹ̀ mi tún rí i.
Mo bẹ̀rẹ̀ sí gbẹ̀ pẹ̀lú bàtà,
nígbàtí àwọn obìnrin náà wà ní ẹsẹ̀kìtì.
Mo yàwòrán wọn.
Mo tún fẹ́ láti gbà àmó lára.
Bí a ṣe ń mú un rọ sí i, mo gbọ́dọ̀ ṣe e.
Oh! Ó dùn tó!


4

Òrò kan: Ọwọ́ (hand)
Má ṣe yàtò sí owó (money).
Àwọn ọwọ́ àwọn obìnrin yìí yálà ṣùgbọ́n ṣí í jù wúrà lọ.






Ohun isẹ́: Ọparun (Bamboo)
Àwọn ọpá bambu tí a fi ń dìdán,
tí a fi ń ṣẹ̀sílẹ̀ àwọn ikoko.

Ọ̀gbọ́n ìrán:

Ìmòlé kan:
Mi ò le gbọ́dọ̀ rí wọn ni isẹ́ ki n máa rántí.
A dé, a jókòó, a wo, a gbà.
Ooru ilé ayé mú kí wọ́n lè se e kánkan,
wọ́n ń jé kí ooru wà títí dòdò yóò rọ.
Ó ṣeé ṣe pé ó ti ṣe ikoko mẹ́wàá lónìí.
Ìṣe, ìrìn, ara rẹ̀ àti àmó.


CLOSURE: Ọjà Ọba

Àwòn ikoko nduro fún àwọn oníbàárà.
Oòrùn n tan wón yí padà sí pupa.
Eruku tí àwọn kẹ̀kẹ́ n gbé sókè n fò ní ojú wọn.
Àwòn kẹ̀kẹ́ kún fún ikoko, tí n fi Ìganran sílẹ̀.
Isé tan.
Kò sí nnkan bí ìwádìí ọja, tàbí àwòrán ìtàjá.
Àwòn ikoko náà n sò fún ara wọn bí wón ti se fún òníyàn látìgbà.

Obinrin àmó

〰️

Obinrin àmó 〰️


ÌDÙPẸ́:
Mo dupẹ́ lọ́wọ́ Ìyá Lẹ́kàn, àwọn aburo rẹ mẹ́rin àti ìyá wọn fún bí wón ti gba wá sílé wọn, tí wón sì pín ìmọ̀ wọn pẹ̀lú wá.
Mo dupẹ́ lọ́wọ́ Fúnmi, Olùṣàkóso ibùgbé ní G.A.S. fún bí ó ti túmọ̀ sí Yorùbá.
Mo dupẹ́ lọ́wọ́ Kavita Chellaram, Kó Gallery àti G.A.S. Foundation fún àǹfààní ìrírí ayé yìí.